Do you want to know the lyrics of Owo Wa by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You're in the right place.
On our website, we have the complete lyrics of the song Owo Wa that you were looking for.
Do you love the song Owo Wa ? Can't quite understand what it says? Need the lyrics of Owo Wa by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You are in the place that has the answers to your desires.
O mi be'ju ironu wo mi, eyi koja owe o (owe o, owe o, owe o eh)
Seb'eni a wi fun k'oba je o gbo, iyen l'abo alakori
L'ai te'ti s'ogbon ipile, a o ti'ka ete ba'nu po l'ojo kan o (ye o, yeh o, eh)
O pe mo ti nba o so, ijo wo lo ma gbo awe o?
T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa
Oju orun ma su dede ara gbola ajanilaya
(Ye o, ye o, ye o, ye)
T'a ba le yi'wa pada ona atunse a la gerere
A o t'omo s'ona iye, eemo o se ni wo'le wa ba ni l'osan gangan (Ye o, ye o, eh)
O wa nwo mi pakopako, emi lo a fe ntun ma wi?
T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa
T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa
Owo wa, owo wa, owo wa lo wa
Owo wa, owo wa, owo wa lo wa
Owo wa, owo wa, owo wa lo wa
Owo wa, owo wa, owo wa lo wa
Owo wa, owo wa, owo wa lo wa
Otras canciones de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band
The most common reason to want to know the lyrics of Owo Wa is that you really like it. Obvious, right?
When we really like a song, as might be your case with Owo Wa by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , we wish to be able to sing it knowing the lyrics well.
A very common reason to search for the lyrics of Owo Wa is the fact that you want to know them well because they make you think of a special person or situation.
It's important to note that Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , in live concerts, has not always been or will be faithful to the lyrics of the song Owo Wa ... So it's better to focus on what the song Owo Wa says on the record.