Lyrics of ' Onlana ' by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Do you want to know the lyrics of Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You're in the right place.

Do you love the song Onlana ? Can't quite understand what it says? Need the lyrics of Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You are in the place that has the answers to your desires.

Mò ń lọ l'óko, mi ò mà l'ẹ'nìkankan
Mò ń w'ọ'nà f'ára mi
Mò ń là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'
Mò nṣè'wọn tí mo lè ṣe
Bí mo bá ń bọ' l'óde, ma ṣè'bà f'ágbàgbà
E mi ò dè'nà m'ẹ'nìkankan
Mò ń w'ọ'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'

Mò nṣè'wọn tí mo lè ṣe
Kí'lé ayé wa dùn k'ó l'áyọ'
K'a ṣè'wọn t'a lè ṣe
K'a fì iyókù sí'lẹ'
K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'

K'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ' idera) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-ayọ', idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ' idẹra)

Ẹgbẹ' oníre l'àwa ń bá rìn
Àwa ò gbìmọ' àdánìkanjẹ
À ngbèrò k'ó lè da o
A mí ṣè'tò kí aṣálẹ' k'ó dì ilú olóyin
Ẹ jẹ' a gbé'ra ní'lẹ', k'á má ṣ'ọ'lẹ

K'a ṣè'wọn t'a lè ṣe
K'a fì iyókù sí'lẹ'
K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'
K'a lè j'ogún ìdẹ'ra pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ̀ idera) k'a j'èrè ìbàlẹ' okàn pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ̀ idẹra) k'a lè j'ogún ìmolẹ' tí bo'rí òkùnkùn biri

Mò ń lọ l'óko, mi ò mà l'ẹ'nìkankan
Mò nw'ọ'nà f'ára mi
Mò ń là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'
Mò ń ṣè'wọ'n tí mo lè ṣe o
Bí mo bá ń bọ' l'óde, ma ṣè'bà f'ágbàgbà
E mi ò dè'nà m'ẹ'nìkankan
Mò ń w'ọ'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ'

Mò ń ṣè'wọ'n tí mo lè ṣe
Kí'lé ayé wa dùn, k'ó l'áyọ
K'a ṣè'wọ'n t'a lè ṣe
K'a fì iyókù sí'lẹ'
K'a là'nà f'ẹ'ni t'ó ń bọ

K'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ̀ idẹra) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' o
(Ah-ayọ̀, idẹra) k'a j'èrè ìbàlẹ' ọkàn, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ' idẹra) k'a lè j'ogún ìdẹ'ra, pẹ'l'áyọ' o, pẹ'l'áyọ' o
(Ah-aah, ayọ' idẹra) k'a lè j'ogún ìmolẹ' tí bo'rí òkùnkùn biri
(Ah-aah, ayọ' idẹra)

Pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ' (ah-aah, ayọ' idẹra)
(ah-aah, ayọ' idera) pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ
(ah-aah, ayọ' idẹra)
(ah-aah, ayọ' idẹra) pẹ'l'áyọ', pẹ'l'áyọ
(Ah-aah, ayọ' idẹra)
(Ah-aah, ayọ' idẹra)

Play Escuchar " Onlana " gratis en Amazon Unlimited

Knowing what the lyrics of Onlana say allows us to put more feeling into the performance.

If your motivation for searching for the lyrics of the song Onlana was that you absolutely love it, we hope you can enjoy singing it.

Feel like a star singing the song Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , even if your audience is just your two cats.

A very common reason to search for the lyrics of Onlana is the fact that you want to know them well because they make you think of a special person or situation.

In case your search for the lyrics of the song Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band is because it makes you think of someone in particular, we suggest you dedicate it to them somehow, for example, by sending them the link to this website, they'll surely get the hint.

Something that happens more often than we think is that people search for the lyrics of Onlana because there is some word in the song they don't quite understand and want to make sure of what it says.

Are you arguing with your partner because you understand different things when you listen to Onlana ? Having the lyrics of the song Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band at hand can settle many disputes, and we hope that it will.

Remember that whenever you need to know the lyrics of a song, you can always turn to us, as has happened now with the lyrics of the song Onlana by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band .