Lyrics of ' Alasela ' by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Do you want to know the lyrics of Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You're in the right place.

On our website, we have the complete lyrics of the song Alasela that you were looking for.

Alasela is a song by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band whose lyrics have countless searches, so we decided it deserves its place on this website, along with many other song lyrics that internet users want to know.

Do you love the song Alasela ? Can't quite understand what it says? Need the lyrics of Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band ? You are in the place that has the answers to your desires.

Bí mo bá ti r'éni mi, inú mi á dùn, ara mi á yá gágá
Ma r'wérín ayò, ma r'érín ìdùnnú, ma k'ọrin tuntun
Bí mo bá ti r'ẹ'ni mi, inú mi á dùn dé lẹ', ara mi á yá gágá
Ma j'íjó ayò, ma r'érín ìdùnnú

Jomijòkè ọlọ'wó-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mọ'
Ojú ayé ti là, gbé'ra ko pàdé mi lóde
Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mọ'
Ọ'nà ọ'tun ti là, bóóde jàre

Wá ká lọ s'ójà ìdẹ'ra, ká mú 're bò wálé
Ọjọ' òní ọjó aláselà mà ló jẹ'
Wá ká lọ s'ókè ìdùnnú, ká m'áyò bò wá lé
Ọjó òní ọjọ' olóyin

Jomijòkè ọlówó-aró, ẹni mi àtàtà, ọjọ' ti mó
Ojú ayé ti là, m'áṣọ wò pàdé mi lóde
Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó
Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre

Wá ká lọ s'ódò ìségun, ká f'àwòn kó're
Ọjọ' òní ọjọ' aláṣelà mà ló jẹ'
Wá ká lọ s'ọ'dọ' àgbà, k'ón súre fún wa
Ọwó àwa t'olúborí ni

Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjọ' ti mọ'
Ojú ayé ti là, múra ko pàdé mi lóde
Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó
Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre

Wá ká lọ s'ókè ìlera, k'ágbára d'ọ'tun
Ọjọ' òní ọjọ' àláfíà mà ló jẹ'
Wá ká lọ s'ọ'gbà ìtura b'óòrùn bá wọ' tán
Ká jó ká yọ', ijó alábùkún

Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mó
Ojú ayé ti là, m'ásọ wò pàdé mi lóde
Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mó
Ònà òtun ti là, bóóde jàre
Jomijòkè ọlọ'wọ'-aró, ẹni mi àtàtà, ọjó ti mọ'
Ojú ayé ti là, gbé'ra ko pàdé mi lóde
Òfaragbìjà, alápá-ajé, aya mi àtàtà, ojú ti mọ'
Ònà ọ'tun ti là, bóóde jàre

Play Escuchar " Alasela " gratis en Amazon Unlimited

When we really like a song, as might be your case with Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , we wish to be able to sing it knowing the lyrics well.

A very common reason to search for the lyrics of Alasela is the fact that you want to know them well because they make you think of a special person or situation.

In case your search for the lyrics of the song Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band is because it makes you think of someone in particular, we suggest you dedicate it to them somehow, for example, by sending them the link to this website, they'll surely get the hint.

It's important to note that Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , in live concerts, has not always been or will be faithful to the lyrics of the song Alasela ... So it's better to focus on what the song Alasela says on the record.

On this page, you have at your disposal hundreds of song lyrics, like Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band .

Learn the lyrics of the songs you like, like Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band , whether it's to sing them in the shower, make your covers, dedicate them to someone, or win a bet.

Remember that whenever you need to know the lyrics of a song, you can always turn to us, as has happened now with the lyrics of the song Alasela by Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band .